Yoruba Service (Gbohunmi)
Yoruba
Gbohunmi je eto iyin, ijosin, ise iranse ati adura ni ede Yoruba. A da eto naa silẹ ni Oṣu Kẹjọ ọdun 2014, nipasẹ itọsọna ti Ẹmi Mimọ, eto naa si nlọ lati ipá de ipá bi awọn eniyan ṣe npadawa lati jẹri agbara ati otitọ Ọlọrun ninu igbesi aye wọn ati awọn ipo wọn.
Gbohunmi jẹ eto ori ayelujara, ti o maa n waye ni ẹẹkan loṣoṣo ni Satidee ti o kẹhin ni gbogbo oṣu. Jọwọ darapọ mọ wa lati ni iriri Ọlọrun ti o ngbọ ti o si dahun adura, ati pe ariwo rẹ ti 'Hallelujah' ko ni pari ni orukọ Jesu.
English
Gbohunmi is a program of praise, worship, ministration, and prayers in Yoruba language. The program was established in August 2014, through the leading of the Holy Spirit and has been going from strength to strength as people return to testify of God's power and faithfulness in their life and circumstances.
Gbohunmi is an online program, which takes place once a month on the last Saturday of every month. Please join us to experience the God that hears and answers prayers, and your shout of ‘Hallelujah’ will never cease in Jesus Name.
Your Generosity Matters
We believe that generosity is part of our worship to God.